Àwọn Ìdíje Òlímpíkì Ìgbà Oru 2004
From Wikipedia, the free encyclopedia
Àwọn Ìdíje Òlímpíkì Ìgbà Oru 2004, lonibise bi Awon Idije Olimpiadi 28k, je idije pataki akariaye oniere-idaraya pupo to waye ni Athens, Greece lati August 13 de August 29, 2004 pelu motto Welcome Home. Awon elere-idaraya 10,625 ni won kopa nibe,[1] eyi fi 600 ju iye ti won reti lo, awonn wonyi je titele leyin pelu awon osise egbe 5,501 lati orile-ede 201.[1] Idije 301 fun eso waye ninu awon ere-idaraya 28.[1] Athens odun 2004 ni igba akoko lati igba Awon Idije Olimpiki Igba Oru 1996 ti gbogbo awo orile-ede ti won ni Igbimo Olorile-ede Olimpiki kopa. Bakanna o tun je igba akoko lati odun 1896 (leyin Idije 1906 to ti je riresile latigba na) ti awon Idije Olimpiki waye ni Girisi.
Quick Facts Ìlú agbàlejò, Motto ...
Ìlú agbàlejò | Athens, Greece |
---|---|
Motto | Welcome Home |
Iye àwọn orílẹ̀-èdè akópa | 201[1] |
Iye àwọn eléré ìdárayá akópa | 10,625[1] |
Iye àwọn ìdíje | 301 in 28 sports |
Àjọyọ̀ ìbẹ̀rẹ̀ | August 13 |
Àjọyọ̀ ìparí | August 29 |
Ẹni tó ṣíi | Ààrẹ Konstantinos Stephanopoulos |
Ìbúra eléré ìdárayá | Zoi Dimoschaki |
Ìbúra Adájọ́ | Lazaros Voreadis |
Ògùnṣọ̀ Òlímpíkì | Nikolaos Kaklamanakis |
Pápá Ìṣeré | Olympic Stadium |
Close