Ọjọ́ Rú
From Wikipedia, the free encyclopedia
Ọjọ́ Rú je ọjọ́ ọ̀sẹ̀ tí ó tẹ̀lé ọjọ́ Ìsẹ́gun ṣùgbọ́n tí ó ṣíwájú Ọjọ́bọ̀. Ní ìbámu pẹ̀lú àjọ àgbáyé ti ISO 8601, òun ni ọjọ́ kẹta nínú ọ̀sẹ̀. Àwọn orílẹ̀-èdè tó fi Ọjọ́ Àìkú ṣe ọjọ́ àkọ́kọ́, gẹ́gẹ́ bí ó ṣe wà nínú Ẹ̀sìn Islam àti àwọn ará Júù, ọjọ́ Rú ni ọjọ́ kẹrin wọn. [1]