Agustín Pedro Justo
From Wikipedia, the free encyclopedia
Agustín Pedro Justo Rolón tí wọ́n bí ní ọjọ́ kẹrìndínlọ́gbọ̀n oṣù kejì ọdún 1976 jẹ́ Ààrẹ apàṣẹwàá orílẹ̀-èdè Argentina tẹ́lẹ̀ láàrin ọdún 1932 sí 1938, ó sì tún jẹ́ olóṣèlú pẹ́lú ni.[1] Justo kòpa nínú ìdìtẹ̀-gbàjọba ti ọdún 1930, lẹ́yìn èyí ni ó di Ààrẹ pẹ́lú ìdìbò èrú. Ó jẹ Ààrẹ láàrín ọdún 1930 sí ọdún 1943. Òun ni ó da country's central bank sílẹ̀ tí ó sì da gbígba owó-orí sílẹ̀ pẹ̀lú.[2]
Agustín Pedro Justo | |
---|---|
President of Argentina | |
In office 20 February 1932 – 19 February 1938 | |
Vice President | Julio Argentino Pascual Roca |
Asíwájú | José Félix Uriburu |
Arọ́pò | Roberto M. Ortiz |
Minister of War | |
In office 12 October 1922 – 12 October 1928 | |
Ààrẹ | Marcelo Torcuato de Alvear |
Asíwájú | Julio Moreno |
Arọ́pò | Luis Dellepiane |
Àwọn àlàyé onítòhún | |
Ọjọ́ìbí | (1876-02-26)26 Oṣù Kejì 1876 Concepción del Uruguay, Entre Ríos |
Aláìsí | 11 January 1943(1943-01-11) (ọmọ ọdún 66) Buenos Aires, Argentina |
Ọmọorílẹ̀-èdè | Argentine |
Ẹgbẹ́ olóṣèlú | UCR-A |
Other political affiliations | Concordancia |
Profession | Military |
Signature | |
Military service | |
Branch/service | Argentine Army |
Years of service | 1892–1931 |
Rank | Major General |
Ó yan olórí ìjọba Marcelo Torcuato de Alvear, pẹ̀lú ìrírí rẹ̀ lábẹ́ ìjọba alágbádá, ati ipa rẹ̀, wọ́n yàn án gẹ́gẹ́ bíi 1931 campaign. Wọ́n yàn án gẹ́gẹ́ bí Ààrẹ ní ọjọ́ kẹjọ oṣù kọkànlá ọdún 1931, pẹ́lú Ìfọwọ́sowọ́pọ̀ ẹgbẹ́ òṣèlú (Partido Demócrata Nacional), Radical Civic Union (Unión Cívica Radical) (UCR), àti Socialist Independent Party (Partido Socialista Independiente). Wọ́n fi ẹ̀sùn ìṣèrú ìbò tí wọ́n fún lórúkọ patriotic fraud kàn án láàrín ọdún 1931 àti 1943. Lásìkò yí, àwọn olóṣèlú alátakò bíi Yrigoyen tí ó wá láti ẹgbẹ́ ìṣèlú Radical Civil Union. gbénáwojú ìṣèjọba rẹ̀.[3] Iṣẹ́ takuntakun tí Mínísítà fún ọ̀rọ̀ ilẹ̀ òkèrè rẹ̀ Carlos Saavedra Lamas, ni ó jẹ́ àṣeyọrí pàtàkì fún ìṣèjọba rẹ̀, amọ̀ wọ́n fi ẹ̀sùn àjẹbánu rẹpẹtẹ kan ìṣèjọba rẹ̀ pẹ̀lú bí ó ṣe jọ̀wọ́ ètò ọrọ̀ Ajé orílẹ̀-èdè sọ́wọ́ àwọn British pàá pàá jùlọ ní ìgbà kejì rẹ̀ ọ̀gbẹ́ni Julio A. Roca Jr. ṣe tọwọ́ bọ̀wé àdéhùn Roca-Runciman Treaty.