Bíbí ọmọ gboju obo (Vaginal delivery)
From Wikipedia, the free encyclopedia
Fún vaginal delivery in pharmacology, ẹ wo Intravaginal administration.
Bíbí ọmọ gbojú obò, (vaginal delivery) ni ọ̀nà ọmọ bíbí gba obò tí àwọn ẹranko afọ́mọlọ́mú àti ènìyàn máa ń bímọ. Wọ́n tún lè pè é ní ọmọ bíbí gbojú ara[1] Ó jẹ́ ọ̀nà ìgbàbímọ́ tí ó wọ́pọ̀ jùlọ káàkiri àgbáyé L.[2] Wọ́n gbà pé òun ló rọrùn julọ láti bímọ ju iṣẹ́-abẹ lọ[3]