Heineken Lokpobiri
Olóṣèlú / From Wikipedia, the free encyclopedia
Heineken Lokpobiri jẹ́ olóṣèlú ọmọ orílẹ̀ èdè Nàìjíríà tí wọ́n dìbò yàn wọlé gẹ́gẹ́ bí aṣojú Ìwọ̀ oòrùn Balyesa ní ilé ìgbìmọ̀ aṣòfin àgbà ti ilẹ̀ Nàìjíríà. Ó jẹ́ aṣojú ní ilé ìgbìmọ̀ aṣòfin lẹ́yìn tí ó wọlé látàrí ètò ìdìbò ti oṣù kẹrin ọdún 2007 lábẹ́ ẹgbẹ́ òṣèlú People's Democratic Party.[1][2][3]
Quick Facts Aṣojú Ìwọ̀ oòrùn Balyesa ní ilé ìgbìmọ̀ aṣòfin àgbà ti ilẹ̀ Nàìjíríà, Constituency ...
Heineken Lokpobiri | |
---|---|
Aṣojú Ìwọ̀ oòrùn Balyesa ní ilé ìgbìmọ̀ aṣòfin àgbà ti ilẹ̀ Nàìjíríà | |
Lọ́wọ́lọ́wọ́ | |
Ó gun orí àga Oṣù kẹrin Ọdún 2007 | |
Constituency | Ìwọ̀ oòrùn Bayelsa |
Àwọn àlàyé onítòhún | |
Ọjọ́ìbí | Ọjọ́ kẹta Oṣù Kẹta Ọdún 1967 |
Ẹgbẹ́ olóṣèlú | People's Democratic Party (PDP) |
Occupation | Amòfin àti Olóṣèlú |
Close