Hjalmar Branting
From Wikipedia, the free encyclopedia
Karl Hjalmar Branting (ìrànwọ́·ìkéde) (23 Oṣù Bélú 1860 – 24 Oṣù Èrèlé 1925) jẹ́ ará Swídìn olóṣèlú. Ó ti jẹ́ olórí Ẹgbẹ́ Sosial Demokratik Swídìn (1907–1925), àti Alákòóso Àgbà ti ìlú Swídìn nígbà emeta ọ̀tọ̀ọ̀tọ̀ (1920, 1921–1923, àti 1924–1925). Bákan náà ó ti gba Ẹ̀bùn Nobel fún Àlàáfíà.
Quick Facts 16th Prime Minister of Sweden, Asíwájú ...
Hjalmar Branting | |
---|---|
16th Prime Minister of Sweden | |
In office 10 March 1920 – 27 October 1920 | |
Asíwájú | Nils Edén |
Arọ́pò | Louis De Geer |
In office 13 October 1921 – 19 April 1923 | |
Asíwájú | Oscar von Sydow |
Arọ́pò | Ernst Trygger |
In office 18 October 1924 – 24 January 1925 | |
Asíwájú | Ernst Trygger |
Arọ́pò | Rickard Sandler |
Àwọn àlàyé onítòhún | |
Ọjọ́ìbí | (1860-11-23)23 Oṣù Kọkànlá 1860 Stockholm |
Aláìsí | 24 February 1925(1925-02-24) (ọmọ ọdún 64) |
Ẹgbẹ́ olóṣèlú | Social Democrats |
(Àwọn) olólùfẹ́ | Anna Branting (née Jäderin) |
Signature |
Close