Òkè Olúmọ
From Wikipedia, the free encyclopedia
Òkè Olúmọ ni òkè kan tí nó wà ní ilẹ̀ Ẹ̀gbá ìlú Abẹ́òkúta tí ó jẹ́ olú ìlú Ìpínlẹ̀ Ògùn ní apá ìwọ̀ Oòrùn ilẹ̀ Nàìjíríà. Òkè Olúmọ jẹ́ ibìsálà fún àwọn ará Abẹ́òkúta ní àsìkò ogun abẹ́lé ní àsìkò 19th century. Wọ́n sì ń bọ òkè náà gẹ́gẹ́ bí Òrìṣà tí wọ́n sì ń bọọ́ pẹ̀lú oríṣríṣi ẹbọ.[1]