Ìbánisọ̀rọ̀
From Wikipedia, the free encyclopedia
Remove ads
Ìbánisọ̀rọ̀ (láti inú èdè Látìnì :communicare,[1] tí ó túmọ̀ sí (ṣíṣalábàápín) jẹ́ ìgbésẹ̀ gbígbé is the act of conveying ìtumọ́ ọ̀rọ̀ láti ọ̀dọ̀ ẹnìkan sí ẹlòmíràn fún ìgbọ́ra-ẹni yé, yálà nípa lílo òfin tí a fiblọ́ọ́lẹ̀ nípa àmì tàbí ìṣesí tí gbogbo wa fọ́wọ́ sí. Àwọn ìgbésẹ̀ tó ṣe kókó nínú ìlànà ìbánisọ̀rọ̀ ni:[2]
- Kẹ́ṣẹ́ tàbí ìdí tí ìbánisọ̀rọ̀ fi wáyé.
- Iṣẹ́ tí a fẹ́ fi ìbánisọ̀rọ̀ yí rán jáde sí olùgbọ́ wa.
- Kókó tí a fẹ́ fi múlẹ̀ inú iṣẹ́ tí a rán jáde.
- Bí a ṣe ránṣẹ́ náà jáde tàbí ọ̀nà tí a gbà gbé iṣẹ́ náà léde.
- Ariwo. Èyí ma ń mú ìdíwọ́ wá nínú ìgbésẹ̀ ìbára-ẹni sọ̀rọ̀, tí kìí sì jẹ́ kí á gbọ́ ara ẹni é bí a bá ń sọ̀rọ̀ lọ. Ariwo yí lè jẹ́ ìmọ̀ọ́mọ̀ ṣe tàbí àìmọ̀ọ́mọ̀ ṣe.[3]
- Àgbékalẹ̀ iṣẹ́ tí a fẹ́ rán sí olùgbọ́ wa tí yóò fi gbọ́nwa yé yéké-yéké
- Àgbọ́yé iṣẹ́ tí olùfiránṣẹ́ fi ránṣẹ́ síwa lásìkò ìbánisọ̀rọ̀.
- Ìtumọ̀: bí a ṣe fún èyíkéyí iṣẹ́ tí agbọ́ àti bí ó ṣe yé wa sí ni yóò dá lórí irúfẹ́ ìtumọ́ ti a lè fún iṣẹ́ gbọ́ náà.
Remove ads
Àwọn Ìtọ́ka sí
Wikiwand - on
Seamless Wikipedia browsing. On steroids.
Remove ads