Òṣogbo

Olú Ìlú ìpínlè Osun àti ìjoba agbègbè ìbílè ní orílè-èdè Nàìjíríà From Wikipedia, the free encyclopedia

Òṣogbo
Remove ads

Òṣogbo jẹ́ ìlú ńlá kan ní ìpílẹ̀ Ọ̀ṣun ní orílẹ̀-èdè Nàìjíríà, bákan náà ni ó jẹ́ olú ìlú fún ìpínlẹ̀ náà ní apá ìwọ̀ Oòrùn ilẹ̀ Nàìjíríà. Ọ̀gbẹ́ni Adémó̩lá Adélékè ni Gómìnà Ìpínlẹ̀ Ọ̀ṣun lọ́wọ́lọ́wọ́. Òṣogbo di olú ìlú fụ́n Ìpínlẹ̀ Ọ̀ṣun ní ọdun 1991.[1] Bákan náà ni ó tún jẹ́ olú ilé-iṣẹ́ ìjọba ìbílẹ̀ fún ìlú Òṣogbo, tí ilé-iṣẹ́ ìjọba ìbílẹ̀ náà sì wà ní Òke Báálẹ̀, nígbà tí ìjọba ìbílẹ̀ Ọlọ́rundá ń ṣojú agbègbè Ìgbóǹnà nílú Òṣogbo.[1][2]

Thumb
Oba Jimoh Olanipekun Oyetunji, Laroye II Ataoja Oshogbo-min


Thumb
Òṣogbo (2015)
Thumb
Location of Osogbo in Nigeria
Ìtàn ṣókí nípa Ìlú Òṣogbo láti ẹnu ọmọ bíbí Òṣogbo
Remove ads

Àwọn ìtọ́ka sí

Loading related searches...

Wikiwand - on

Seamless Wikipedia browsing. On steroids.

Remove ads