Ẹ̀fọn
From Wikipedia, the free encyclopedia
Remove ads
Ara àwon kòkòrò tí ó n fò ni èfọn. Wón tún máa ń pè é ní yànmùyánmú.[1] Àwọn ẹ̀fọn burú gan-an ni nítorí pé wọ́n máa ń tan àìsàn ká. Ẹ̀fọn tí ó bá jẹ́ akọ kò léwu. Ẹ̀fọn tí ó bá jẹ́ abo ni ó máa ń fa ẹ̀jẹ̀ ènìyàn tàbí ti ẹranko mu. Ibi tí ó ti ń fa ẹ̀jẹ̀ mu yìí ni ó ti máa ń tan àìsàn ká. Àwọn ẹ̀fọn kan máa ń tan malaria ká. Àwọn kan máa ń tan ibà apọ́njú ká.
Orí omi ni àwọn ẹ̀fọn máa ń yé sí. Lẹ́yìn òṣẹ̀ kan sí márùn-ún, ẹyin yìí yóò pa yóò di ‘larvae’, eléyìí ní yóò di ‘pupae’ kí ó tó wá di ẹ̀fọn lẹ́yìn ọjọ́ mẹ́ta.[2]
A le fín oògùn sí ẹ̀fọn láti pa á tàbí kí a máa jẹ́ kí ó rí omi yé sí tàbí kí a máa sin àwọn ẹja kan tí ó máa ń jẹ ẹyin wọ̀nyí. Ti a ba fe sun, a le fi awon yi beedi wa po ki efon ma baa ri aye wole lati je wa.
Gege bi imo se fi lole, abo efon ni o maa n fa aisan iba lara eniyan.[3]
![]() |
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |
Remove ads
Itokasi
Wikiwand - on
Seamless Wikipedia browsing. On steroids.
Remove ads