Ẹ̀kọ

Agidi tabi Eko jẹ ounjẹ Naijiria ti a ṣe pẹlu iyẹfun oka. From Wikipedia, the free encyclopedia

Ẹ̀kọ
Remove ads

Ẹ̀kọ jẹ́ oúnjẹ tí ó gbajúmọ̀ ní Nàìjíríà, tí wón sì ń fi àgbàdo, ọkà tàbí jéró ṣe.[1][2][3][4] Bí wọ́n bá fẹ́ se ògì, wọ́n á rẹ àgbàdo,, ọkà tàbí jéró sínú omi fún ọjọ́ méjì sí mẹta kí wón tó lọ̀ ọ́, lẹ́yìn náà, wọ́n ọ́ fi kalẹ̀ fún bí í ọjọ́ mẹ́ta mìíràn láti kan, lẹ́yìn èyí, wọ́n le sè é. Wọ́n máa ń fi àkàrà, mọ́ín mọ́ín àti àwọn oúnjẹ míràn mu ẹ̀kọ.

Quick facts Alternative names, Type ...
Thumb
Ẹ̀kọ tútù
Remove ads

Àwon Ìtókasí

Loading related searches...

Wikiwand - on

Seamless Wikipedia browsing. On steroids.

Remove ads