Ẹ̀pà
From Wikipedia, the free encyclopedia
Remove ads
Ẹ̀pà jẹ́ ohun jíjẹ eléso ti a ń rí láti inú ilẹ̀ , tí àwọn ọmọ rẹ̀ sì ma ń wà nínú apó tàbí èpo (pord). Òun àti ẹ̀wà pèlú gbogbo ìran tí wọn bá pín sí jẹ́ ọmọ ìyá kan náà. oríṣiriṣi orúkọ ni àwọn elédè àgbáyé ń pèé. [1] [2]
Wikiwand - on
Seamless Wikipedia browsing. On steroids.
Remove ads