Aṣọ

From Wikipedia, the free encyclopedia

Remove ads

Aṣọ jé ohun tí ènìyàń ń wọ̀ láti bo ìhòhò. Oríṣi ohun èlò ni a fi ń hun aṣọ, àwọn ohun èlò bíi òwú, ọ̀rá, awọ sílìkì[1] àti bẹ́ẹ̀bẹ́ẹ̀ lọ, lẹ́yìn híhun aṣọ, aṣọ tún nílò rírán kí ó tó le di wíwọ̀. Yàtò sí fún bíbo ìhòhò, aṣọ tún wà fún oge àti ìdánimọ. Àpẹẹrẹ oríṣi aṣọ ilé Yorùbá ni ìró àti bùbá, Agbádá, dànsíkí, búbù, kẹ̀mbẹ̀, àti bẹ́ẹ̀ bẹ́ẹ̀ lọ. (ní òpòlopò ìgbà) olùwọ àwọn asọ wọ̀nyí ma ń jé ọmọ Yorùbá [2] [3].

Remove ads

Orisirisi aso ní ilè Yorùbá

Ìró àti Bùbá

Agbádá

Ìpèlé

Àwon Ìtókasí

Loading related searches...

Wikiwand - on

Seamless Wikipedia browsing. On steroids.

Remove ads