Abdelkader Taleb Oumar

From Wikipedia, the free encyclopedia

Abdelkader Taleb Oumar
Remove ads

Abdelkader Taleb Omar (Lárúbáwá: عبد القادر طالب عمر, ʿAbd āl-Qādar Ṭāleb ʿOmar) ni Alakoso Agba ti Orílẹ̀-èdè Olómìnira Áràbù Sàhráwì (SADR), ni eto bi ijoba-leyi-odi ti Polisario Front gbekale. O je yiyan si ipo na latowo Aare SADR Mohamed Abdelaziz, leyin Ipejo Gbogbo Ololugbe Kokanla to waye ni Tifariti ni ojo 29 Osu Kewa odun 2003.

Quick facts Prime Minister of the Sahrawi Arab Democratic Republic, Ààrẹ ...
Remove ads

Itokasi

Loading related searches...

Wikiwand - on

Seamless Wikipedia browsing. On steroids.

Remove ads