Àbújá
olu-ìlú orílẹ̀-èdè Nàìjíríà From Wikipedia, the free encyclopedia
Remove ads
Àbújá jẹ́ olú-Ìlú fún orílé-èdè Nàìjíríà. Ìlú yí ni ó jẹ́ àrin-gbùngbùn fún orílẹ̀-èdè Nàìjíríà, tí ilé ìjọba àpapọ̀ sì fìdí kalẹ̀ sí ní abẹ́ Aso Rock, Àpáta Agbára ni Àbújá.[1][2] [3][4]. Àbújá dí olú-ìlú orílè-ede Nàìjíríà ní osù kéjìlá, odún 1991, àkọsílẹ̀ ètò ikaniyan ti ọdún 2006 sọ wípé Àbújá ní olùgbé 776,298[5]
Remove ads
Àwọn Ìtọ́kasí
Wikiwand - on
Seamless Wikipedia browsing. On steroids.
Remove ads