Ẹ̀bùn Ọ́skà
From Wikipedia, the free encyclopedia
Remove ads
Àwọn Ẹ̀bùn Akádẹ́mì tàbí Ẹ̀bùn Ọ́skà jẹ́ ẹ̀bùn ìmọ̀ ìjìnlẹ̀ fíìmù tí American Academy of Motion Picture Arts and Sciences ma ń fún olùdarí eré, òṣèrè àtí olùkọ̀tàn fún iṣẹ́ takuntakun ní ilé iṣẹ́ fíìmù.[1] Ayẹyẹ ẹ̀bùn yìí jẹ́ ìkan lára àwọ́n ayẹyẹ èbùn tó lókìkí jùlọ ní gbogbo àgbáyé. Osì tún jẹ́ Ayẹyẹ ẹ̀bùn tó pẹ́ júlọ tí ó si ma ń dàgbeléwò lórí ẹ̀rọ amóùnmáwòran ní orílẹ̀ èdè tó ju igba lọ. Aẁọn ẹ̀bùn ìmọ̀ ìjìnlẹ̀ fíìmù bi tiẹ̀ ni Grammy Awards (fún orin), Emmy Awards (fun amóùnmáwòran), àti Tony Awards (fún tíát̀à)
Remove ads
Ìtọ́kasí
Wikiwand - on
Seamless Wikipedia browsing. On steroids.
Remove ads