Aduge language
From Wikipedia, the free encyclopedia
Remove ads
Èdè Aduge ni wọ́n ń pè ní Adupe tàbí Adong, tí àwọn ará Ìlú Aduge máa ń sọ. Ó jẹ́ èdè kan tí ó wà lára àwọn Èdè tí wọ́n ń sọ ní Ìpínlẹ̀ Plateau lábẹ́ ìsòrí Ede Benue àti Congo, bákan náà ni a lè pín sí Èdè Niger Àti Congo. Àwọn èdè tí ó wà lábẹ́ ìsòrí Èdè Plateau jẹ́ èdè tí wọ́n ń sọ ní àárín orílẹ̀ èdè Nàìjíríà.
Wikiwand - on
Seamless Wikipedia browsing. On steroids.
Remove ads