Agége
From Wikipedia, the free encyclopedia
Remove ads
Agége jẹ́ ìlú kan tí ó wà ní Ìpínlẹ̀ Èkó, tí ó sì tún jẹ́ ìjọba ìbílẹ̀ kan tí wọ́n ṣe àfàyọ rẹ̀ láti ara ìjọba ìbílẹ̀ Ìkẹjà ní orílẹ̀-èdè Nàìjíríà.




Remove ads
Ìtàn Agége
Agége jẹ́ ìlú kan tí ó ti wà tipẹ́, wọ́n ọ ìlú náà ní orúkọ nígbà ti iná òwò òwò obì ṣe ń jo gerege níléẹ̀ [[Nàìjíríà] Àwọn tí wọ́n ta ìlú yí do ni àwọn ènìyàn Àwórì àmọ́, irú wá ògìrì wá ọ̀pọ̀lọpọ̀ ènìyàn pàá pàá jùlọ àwọn Hausa tí wọ́n ma ń ṣòwò Obì. Lára àwọn Hausa yí ni wọ́n ma ń gé igi tí wọ́n sì tún ma ń káà. Nígbà kúùgbà tí àwọn ènìyàn Yorùbá bá ti nílò láti gé tàbí la igi, wọ́n ma ń pe àwọn Hausa láti ṣe àwọn iṣẹ́ wọ̀nyí, ó pẹ̀ tí àwọn Hausa yí ti ń gbé ní ibẹ̀ tí wọ́n sì ti ní àdúgbò tí wọ́n yà sọ́tọ̀ fún wọn tí wọ́n pe ní " Ìlú Àwọn Agé igi" , tí wọ́n sè di "Agége" lóní. [1]
Remove ads
Dídá Ìjọba ìbílẹ̀ rẹ̀ kalẹ̀
Wọ́n dá ìjọba ìbílẹ̀ Agége sílẹ̀ ní ọdún 1954, tí ó sì dá wà títí di ọdún 1967 tí àwọn ológun kọ́kọ́ dìtẹ̀ gbàjọba, tí wọ́n sì dàá pọ̀ mọ́ ìjọba ìbílẹ̀ Ìkẹjà. Wọ́n tún yọ Agége kúrò lábẹ́ Ìkẹjà ní ọdún 1980 láboẹ́ ìjọba alágbádá tí ó sì tún dá wà fún ọdún mẹ́ta, lẹ́yìn tí àwọn ológun pa ohun tí ó ń jẹ́ ìjọba ìbílẹ̀ rẹ́ ní inú ètò ìṣèjọba wọn. sí abẹ́ Ìkẹjà nígbà tí wọ́n tún dìtẹ̀ gbàjọba ní ọdún 1983. [2] Lára àwọn ìjọba ìbílẹ̀ tí wọ́n tu dá sílẹ̀ láti ará ìjọba ìbílẹ̀ Agége lábẹ́ ìṣèjọba alágbádá ni:
- Ìjọba ìbílẹ̀ Àlímọ̀ṣọ́,
- Ìjọba ìbílẹ̀ Ìfàkọ̀-Ìjàyè àti
- Ìjọba ìbílẹ̀ Orílé-Agége
Remove ads
Àwọn Àwòrán Nípa Ìlú Agége
- Oba Akran roundabout Agege
- Agege Stadium
- Apá kan ti eré pápá fún gbígbá bọ́òọ̀ù ní Agege
- Obìrin tó ń kiri búrẹ́dì ní Agége
- Ọgbà kan ní ìlú Agége
- Raster fried chicken ní Agege
Àwọn Ìtọ́kasí
Wikiwand - on
Seamless Wikipedia browsing. On steroids.
Remove ads
