Agbègbè Ìjọba Ìbílẹ̀ Obafemi-Owode
From Wikipedia, the free encyclopedia
Remove ads
Obafemi Owode jẹ́ ọ̀kan nínú àwọn ìjọba ìbílẹ̀ tó wà ní Ìpínlẹ̀ Ògùn, tí a ṣẹ̀dá lẹ́yìn òfin No.9 of 1976, èyí tí ó jé áyorísi tí òfin ìjọba ìbílẹ̀ tí ọdún 1976. Síwájú ákoko yìí, ètò òṣèlú agbègbè yìí wá ní abẹ́ ìṣàkóso àṣẹ ìletò Owódé àti ìletò Obafemi.

Remove ads
Àwọn ìtọ́kasi
Wikiwand - on
Seamless Wikipedia browsing. On steroids.
Remove ads