Hóró
ẹ̀ka Wikimedia From Wikipedia, the free encyclopedia
Remove ads
Hóró[1] jẹ́ ẹyọ aládìmú àti oníàmúṣe fún gbogbo àwọn ohun ẹlẹ́ẹ̀mì tí a mọ̀. Òhun ni ẹyọ ẹ̀mí tó kéréjùlọ tó jẹ́ tò sọ́tọ̀ bí i ohun alàyè, wọ́n sì tún ùnpé bíi òkúta ìkọ́ ẹ̀mí.[2] Àwọn ohun ẹlẹ́ẹ̀mí ṣe é tò sọ́tọ̀ bíi oníhórókan (consisting of a single cell; èyí kàkún ọ̀pọ̀ àwọn baktéríà) tàbí oníhórópúpọ̀ (èyí kàkún àwọn ọ̀gbìn àti ẹranko). Ara àwọn ọmọ ènìyàn ní bíi ẹgbẹgbẹ̀rúnkẹta 100 hóró; ìtóbi hóró jẹ́ 10 µm nígbàtí ìkórajọ hóró jẹ́ 1 nanogram.
![]() |
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |

Awọn Apáanú :
1. Nucleolus
2. Kóróonú
3. Ríbósómù
4. Vesicle
5. Τραχύ Endoplasmic reticulum (ΕΔ)
6. Ohun èlò Golgi
7. Ọ̀págun-hóró
8. Λείο Endoplasmic reticulum
9. Mitokọ́ndríà
10. vacuole
11. cytoplasm
12. Lísósómù
13. centrioles.
Cellular membrane lo yi ahamo ka
Remove ads
Itokasi
Wikiwand - on
Seamless Wikipedia browsing. On steroids.
Remove ads