Amẹrísíọ̀m

From Wikipedia, the free encyclopedia

Amẹrísíọ̀m
Remove ads

Amẹrísíọ̀m tabi Americium je apilese alasopapo to ni ami-idamo Am ati nomba atomu 95. Gege bi apilese onide alagbararadio, americium je aktinidi ti o je bibosowo Glenn T. Seaborg ni 1944 nigba to n digbolu plutonium pelu awon neutroni be sini o je apilese teyinuraniom kerin to je wiwari. Won soloruko fun orile Amerika, ni ibaramu mo europium.[1]

Quick facts Americium, Pípè ...
Remove ads

Itokasi

Loading related searches...

Wikiwand - on

Seamless Wikipedia browsing. On steroids.

Remove ads