Ìjọba àìlólórí
From Wikipedia, the free encyclopedia
Remove ads
Ìjọba àìlólórí (Anarchy, ἀναρχίᾱ anarchíā) le je ikan ninu iwonyi:
- "Ko si olori tabi alase kankan."[1]
- Aisi ijoba; ailofin nitori aisi ijoba kankan to le gbofin ro.[2]
- Awujo to je pe ko si eni kankan ni ipo ijoba, sugbon ti olukaluku ni ominira patapata (laisi modaru).[3]
![]() |
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |
Remove ads
Itokasi
Wikiwand - on
Seamless Wikipedia browsing. On steroids.
Remove ads