Àndórà

From Wikipedia, the free encyclopedia

Àndórà
Remove ads

Àndórà tabi fun iseoba o je Ilẹ̀-Ọmọba Andorra, bakanna won tun mo si Ilẹ̀-Ọmọba àwọn Àfonífojì ilẹ̀ Àndórà[1] (Principality of the Valleys of Andorra) je orílẹ̀-èdè aláfilẹ̀yíká ni apa guusuiwoorun Europe.

Quick Facts Principality of Andorra Ilẹ̀-Ọmọba Andorra [Principat d'Andorra] error: {{lang}}: text has italic markup (help), Olùìlú àti ìlú tótóbijùlọ ...

Nínú ètò ìkànìyàn 1995, àwọn tí ó ń gbé Àndórà jẹ́ ẹgbẹ̀rún méjì-dún-láàádọrin (68,000). Àwọn èdè tí ó jẹ́ ti ìjọba níbẹ̀ ni Kàtáláànù tí ìpín ọgọ́ta nínú ọgọ́rùn-ún ń sọ (60%) àti èdè faransé. Wọ́n tún ń sọ Kàsìtílíànù ti àwọn Pànyán-àn-àn gan-an fún òwò àgbáyé àti láti fi bá àwọn tí ó bá wá yẹ ìlú wọn wo sọ̀rọ̀ .


Remove ads

Itokasi

Loading related searches...

Wikiwand - on

Seamless Wikipedia browsing. On steroids.

Remove ads