Antonio Gramsci

From Wikipedia, the free encyclopedia

Antonio Gramsci
Remove ads

Antonio Gramsci (Àdàkọ:IPA-it) (January 22, 1891 April 27, 1937) je was an amoye ara Itali, olukowe, oloselu ati oniro oloselu. O je ikan ninu awon oludasile ati olori Egbe Komunisti ile Itali ,o je jiju si ogba ewa latowo ijoba Fasisti Benito Mussolini. Awon iwe kiko re da le lori ituyewo asa ati isolori oloselu. O se pataki gege bi aronu ogidi ninu asa Marksisti. O gbajumo fun ajotunmo hegemoni asa gege bi ona ti orileijoba ninu awujo kapitalisti, be na sini won gba bi akopa koko ninu imoye.

Quick facts Orúkọ, Ìbí ...
Remove ads

Itokasi

Loading related searches...

Wikiwand - on

Seamless Wikipedia browsing. On steroids.

Remove ads