Arigidi Akoko
From Wikipedia, the free encyclopedia
Remove ads
Arigidi je ilu to wa ni Akoko ariwa ìwọ oòrùn Ìpínlẹ̀ Òndó, ni orile-ede Nàìjíríà.[1]

Remove ads
Àwọn ọdún wọn
Ọkọ́ta jẹ́ ìkan lára àwọn ọdún tí o gbajúmọ̀ tí wọ́n ń ṣe ní ìlú Arigidi. Àwọn ẹgbẹ́ Oodua People’s Congress ni ó ma ń ṣe agbátẹrù fún ọdún náà lábẹ́ àṣẹ Iba Gani Adams tí o jẹ́ ọmọ bíbí ìlú Arigidi, ti o si tun jẹ Ààrẹ ọ̀nà kakaǹfò ilẹ Yoruba. Ọdun Okota yí jẹ́ ọdun ti wọ́n fi ń ṣe àtìlẹyìn fún ẹ̀sìn ìbílẹ̀ Yorùbá. Àwọn Ọdun mìíràn tí wọ́n tún ń ṣe ọdún ìjẹṣu ẹ̀yí ma n wáyé ni inú oṣù kéje ,ọdún éègún, ọdún ìbẹ́gbẹ́, ọdún ẹrẹ̀[2][3][4]
Remove ads
Ìṣèlú wọn
Nínú ojúkò ìdìbò mẹ́wá tí ó wà ní apá aríwá ìwọ̀ Oòrùn gúúsù ilẹ̀ Àkókó, Arigidi kò méjì nínú rẹ̀ tí wọ́n ń pè ní Arigidi Iye ward 1 àti Àgbálùkú Ìmọ̀ ward 2 wọ́ọ̀dù kínní ní ìpísísọ̀rí mẹ́rìnlélógún nígbà tí wọ́ọ̀dù kejì Ìpínsísọ̀rí mọ́kànlá tí gbogbo re sì jẹ́ mẹ́rìlálélọ́gbọ̀n lápapọ̀.[5][6]
Àwọn ìtọ́kasí
Wikiwand - on
Seamless Wikipedia browsing. On steroids.
Remove ads
