Àwọn èdè Atlántíkì-Kóngò

From Wikipedia, the free encyclopedia

Remove ads

Ninu iyasoto awon ede Afrika, awon ede Atlántíkì-Kóngò lopojulo ninu awon ede ibatan Niger–Kongo, pelu awon sistemu ikosoto oro-oruko to wopo ninu awon ede Niger–Kongo. O ni gbogbo awon ede Niger–Kongo ayafi Mande, Dogon, Ijoid, ati die ninu Kordofanian.

Quick Facts Atlántíkì-Kóngò, Ìpínká ìyaoríilẹ̀: ...


Remove ads

Itokasi

Loading related searches...

Wikiwand - on

Seamless Wikipedia browsing. On steroids.

Remove ads