Bàbá

From Wikipedia, the free encyclopedia

Bàbá
Remove ads

Bàbá ni ọbí to je ọkùnrin eyan kan. Opolopo awon ẹranko ati eniyan ni won ni ìyá ati baba to bi won.[1][2]

Thumb
Bàbá pelu ọmọ.

Ni awon àṣà miran won pe baba ni okunrin to dagba tabi to nipo ju onitoun lo. Bakanna awon elesin Kristiani n pe ọlọ́run ni baba: "Baba wa ti n be ni orun"[3]


Remove ads

Itokasi

Loading related searches...

Wikiwand - on

Seamless Wikipedia browsing. On steroids.

Remove ads