Bàtà
From Wikipedia, the free encyclopedia
Remove ads
Bàtà jẹ́ ohun tí ọmọ ènìyàn ma ń wọ̀ sí ẹsẹ̀ láti lè fi rìn ati láti se dáàbòbò ẹsẹ̀ kúrò lọ́wọ́ ìjàmbá tó lè ṣakóbá fún ẹsẹ̀ [1]


Ìwúlò bàtà
Wọ́n ma ń lo bàtà yálà lásìkò ẹ̀rùn tàbí òjò. Wọ́n ń lo bàtà láti fi ṣe iṣẹ́ èyíkéyí, ṣe eré ìdárayá, ṣe ìdáàbòbò ara àti bẹ́ẹ̀ bẹ́ẹ̀ lọ. [2] Láì Ko sí bàtà láyé Òde òní, ó lè ṣòro fún ọmọnìyàn láti ṣe ohunkóhun dára dára bí wọn ko bá wọ bàtà sí ẹsẹ̀.[3]
Àwọn Ìtọ́kasí
Wikiwand - on
Seamless Wikipedia browsing. On steroids.
Remove ads