Bẹ̀rmúdà
From Wikipedia, the free encyclopedia
Remove ads
Bermuda (pípè /bɜrˈmjuːdə/; lonibise bi, àwọn Bẹ̀rmúdà tabi Àwọn Erékùṣù Somers) je ile-agbegbe okere Britani ni Ariwa Okun Atlantiki. O budo si ilaorun etiokun awon Ipinle Aparapo, isupoile to sunmo julo ni Cape Hatteras, North Carolina, bi 1,030 kilometres (640 mi) si iwoorun-ariwaiwoorun. O wa bi 1,373 kilometres (853 mi) guusu Halifax, Nova Scotia, Kanada, ati 1,770 kilometres (1,100 mi) ariwailaorun Miami, Florida. Oluilu re ni Hamilton sugbon ibile titobijulo ni ilu Saint George's.
Bermuda ni ile-agbegbe okere Britani toseku topejulo to si ni olugbe julo, o je bibudo si latowo Ilegeesi ni ogorun odun ki ofin Isoka 1707 to da Ileoba Britani Olokiki aparapo sile. Oluilu Bermuda akoko, St George's, je bibudo sori ni 1612 o si je ilu Ilegeesi ni Amerika topejulo ti awon eniyan ungbe nibe.[3]
Okowo Bermuda dara daada, pelu inawo bi eka okowo re totobijulo, leyin re ni isebewo,[3][4] awon wonyi fun ni GIO tenikookan to gajulo lagbaye ni 2005. O ni ojuojoabeonileoloru .[5]
Remove ads
Itokasi
Wikiwand - on
Seamless Wikipedia browsing. On steroids.
Remove ads