Bósníà àti Hẹrjẹgòfínà

From Wikipedia, the free encyclopedia

Bósníà àti Hẹrjẹgòfínà
Remove ads

Bósníà àti Hẹrjẹgòfínà (pípè /ˈbɒzni.ə (ænd) hɜrtsɨˈɡoʊvɨnə/ ( listen)[5] or /ˌhɜrtsɨɡoʊˈviːnə/;[6] Bosnian, Croatian, Serbian Latin: Bosna i Hercegovina; Bosnian and Serbian Cyrillic: Босна и Херцеговина) je orile-ede ni Guu-Apailaorun Europe, ni Peninsula Balkani. O ni bode mo Kroatia ni ariwa, iwoorun ati guusu, Serbia ni ilaorun, ati Montenegro si guusuilaorun, Bosnia ati Herzegovina (bakanna: Bosnia-Herzegovina/Bosnia ati Hercegovina) je ku di ko je ayikanule, ayafi fun 26 kilometres (16 miles) ebado Omi-okun Adriatiki, ni ilu Neum.[7][8] Abenu orile-ede na je kiki okegiga ni arin ati si guusu, ilegiga ni ariwaiwoorun, ati ile pelebe ni ariwa ilaorun. Ninu na tu ni ibi jeografi totobiju to ni ojuojo orile iloworo, to ni igba orun gbigbona ati igba otutu to ni yinyin. Eti apaguusu re ni ojuojo Mediteraneani ati ojuile pelebe.

Quick facts Bósníà àti Hẹrjẹgòfínà Bosnia and Herzegovina Bosna i HercegovinaБосна и Херцеговина, Olùìlú àti ìlú tótóbijùlọ ...
Thumb
Remove ads

Itokasi

Loading related searches...

Wikiwand - on

Seamless Wikipedia browsing. On steroids.

Remove ads