Common Era
From Wikipedia, the free encyclopedia
Remove ads

CE àti AD jẹ́ kannáà, ṣùgbọ́n àwọn ènìyàn tí ko gbàgbọ́ nínú Jésù Kristi tàbí Ọlọ́run, ni wọ́n ń lo CE dípò AD. Ní èdè Gẹ́ẹ́sì (English) CE èyí túmọ̀ sí «Common Era» ìtumọ̀ ní èdè Yorùbá jẹ́ Àsìkò tó wọ́pọ̀.
Wikiwand - on
Seamless Wikipedia browsing. On steroids.
Remove ads