Akọ̀wé-Àgbà Àjọni àwọn Orílẹ̀-èdè

From Wikipedia, the free encyclopedia

Remove ads

Akowe-Agba Ajoni awon Orile-ede ni olori Ile-ise Akowe Ajoni awon Orile-ede, akorajo gbogbogbo to n sise fun egbe Ajoni awon Orile-ede lati igba idasile re ni odun 1965 to ni ojuse fun sisoju Ajoni ni igboro.[1] Akowe-Agba Ajoni awon Orile-ede yato si Olori Ajoni awon Orile-ede, to je Queen Elizabeth II lowolowo.

Akojo awon Akowe-Agba

More information Oruko, Orile-ede ...


Remove ads

Itokasi

Loading related searches...

Wikiwand - on

Seamless Wikipedia browsing. On steroids.

Remove ads