Coretta Scott King

Olóṣèlú From Wikipedia, the free encyclopedia

Coretta Scott King
Remove ads

Coretta Scott King (April 27, 1927 – January 30, 2006) jẹ́ olùkọ̀wé, alákitiyan, aṣíwájú fún àwọn ẹ̀tọ́ aráàlú ará Amẹ́ríkà, àtí ìyàwó Martin Luther King Jr.. Ó ṣakitiyan fún ìbáradọ́gba àwọn ọmọ African-American, ó ṣe aṣíwájú fún Civil Rights Movement ní 1960s. King tún jẹ́ akọrin tó lo orin nínú iṣẹ́ rẹ̀ fún àwọn ẹ̀tọ́ aráàlú. King bá ọkọ rẹ̀ pàdé nkgbà tí wọ́n jọ wà ní ilé-ẹ̀kọ́ yunifásítì ní Boston.

Quick facts Ọjọ́ìbí, Aláìsí ...


Remove ads

Itokasi

Loading related searches...

Wikiwand - on

Seamless Wikipedia browsing. On steroids.

Remove ads