Ìjọba Dahomey

From Wikipedia, the free encyclopedia

Ìjọba Dahomey
Remove ads

Ìjọba Dahomey ( /dəˈhmi/) jẹ́ ìjọba kan ní ìwọ̀ oòrùn Áfíríkà tí orílẹ̀ èdè Benin wà lọ́jọ́ òní. Ìjọba náà wà láti ọdún 1600 títí di 1904. Wọ́n kó Dahomey sí orí òkè Abomey, ìjọba náà di alágbára lágbègbè rẹ̀ ní àwọn ọdún 1700s, wọ́n sì ségun àwọn ilẹ̀ tí ó wà ní gúúsù wọn láti tan ilẹ̀ wọn, àwọn ilẹ̀ bi Whydah ti ìjọba Whydah tí etí odò Atlantic èyí tí ó mú wọn ní àṣẹ sí àwọn ilẹ̀ tí wọ́n ti ń ṣe triangular trade.

Quick Facts Ìjọba Dahomey, Status ...

Láàrin àwọn ọdún 1800s, ìjọba Dahomey di alágbára àgbègbè náà kí ó tó di pé Ìpínlẹ̀ Oyo.[1]

Àwọn ọmọ orílẹ̀ èdè ní orílẹ̀ Europe tí ó wá sí ilẹ̀ náà kọ ọ̀pọ̀lọpọ̀ nípa rẹ̀. Ìjọba Dahomey jẹ́ alágbára ní agbègbè náà tí ọ̀rọ̀ ajé wọn dá lórí Okoẹrú.

Ìjà ilẹ̀ padà bẹ̀rẹ̀ sí ń ní bọ́yọ̀ láàrin orílẹ̀ èdè France àti ìjọba náà, èyí fa Ìjà Franco-Dahomean àkọ́kọ́ ní ọdún 1890, orílẹ̀ èdè Faransé sì ségun ogun náà. Ìjọba náà padà lólẹ̀ ní ọdún 1894 nígbà tí àwọn ọmọ ogun Faranse pa ọba Dahomey ní ogun Franco-Dahomean kejì.

Remove ads

Àwọn Ìtọ́kasí

Loading related searches...

Wikiwand - on

Seamless Wikipedia browsing. On steroids.

Remove ads