Oṣù Kejìlá

From Wikipedia, the free encyclopedia

Oṣù Kejìlá
Remove ads

Àdàkọ:Kàlẹ́ndà31Ọjọ́Bẹ̀rẹ̀NíỌjọ́ Ajé

Osù:| Kínní | Kejì | Kẹta | Kẹrin | Kàrún | Kẹfà | Keje | Kẹjọ | Kẹ̀sán | Kẹ̀wá | Kọkànlá | Kejìlá

Osù Ọ̀pẹ nínú ònkà oṣù ojú ọ̀run Yorùbá ni ó jẹ́ oṣù Kejìlá nínú ònkà oṣù ojú ọ̀run ti àwọn (Gẹ̀ẹ́sì) tí wọ́n pè ní December Ọjọ́ mọ́kànlélọ́gbọ̀n ni ó wà nínú oṣù yí.

Thumb
December, from the Très Riches Heures du duc de Berry

Osù December ni awọn gẹ̀ẹ́sì fa orúkọ rẹ̀ yọ látara ọ̀rọ̀ ""decem" (tí ó túmọ̀ sí ten) nítorí wípé òun gaan ni oṣù kẹwàá ọdún nínú kalẹ̀dà tí àwọn calendar of Romulus c.750 BC tí ìbẹ̀rẹ̀ oṣù tiwọn sì bẹ̀rẹ̀ ní oṣù kẹta ọdún. Àwọn oṣù tókù kò ti sí tẹ́lẹ̀, amọ́ wọ́n ṣàfikún oṣú kínní ati oṣù kejì kun tí December sì dá dúró ní tirẹ̀. [1]

Remove ads

Àwọn ìtọ́ka sí

Loading related searches...

Wikiwand - on

Seamless Wikipedia browsing. On steroids.

Remove ads