Ìpínlẹ̀ Delta
Ìkan lára àwọn ìpínlẹ̀ ní orílé-èdè Nàìjíríà From Wikipedia, the free encyclopedia
Remove ads
Ipinle Delta jẹ́ ọ̀kanIlára àwọn Ìpínlẹ̀ nií riílẹ̀-èdèNaijiria. Ìpínlẹ̀ Delta wà ní apá Gúúsù Nàìjíríà. Adá Ìpínlẹ̀ ìíkalẹ̀ ní ọjọ́ kẹtàdínlọ́gbọ̀n, oṣù keẹjọ ọdún 1991lábé ìjọba Gen. Ibrahim Babangida [1]. Olú-ìlú Ìpínlẹ̀ Delta ni Asaba, bí ó tilẹ̀ jẹ́ wípé ìlú Warri ni àárín ajé Ìpínlẹ̀ Delta. Àwọn èyà tí ópọ̀ jùlọ í Ìpinlè Delta ni Igbo, Urhobo, Isoko, Ijaw, Itsekiri [2]. Ìpinlè Delta ní Ìjọba Àgbègbè Ìbílè márùndílọ́gbọ̀n (25) [3] Gómìnà Ifeanyi Okowa ní gómìnà Ìpínlẹ̀ Delta lọ́wọ́.
Remove ads
Awon Ìjoba Agbegbe Ìbílè ti Delta
- Ariwa Aniocha
 - Guusu Aniocha
 - Bomadi
 - Burutu
 - Guusu Ethiope
 - Ila-oorun Ethiope
 - Ariwa Ila-oorun Ika
 - Guusu Ika
 - Ariwa Isoko
 - Guusu Isoko
 - Ila-oorun Ndokwa
 - ìwọ̀ oòrùn Ndokwa
 - Okpe
 - Ariwa Oshimili
 - Guusu Oshimili
 - Patani
 - Sapele
 - Udu
 - Ariwa Ughelli
 - Guusu Ughelli
 - Ukwuani
 - Uvwie
 - Ariwa Warri
 - Guusu Warri
 - Guusu ìwọ̀ oòrùn Warri
 
Àwọn olókìkí ènìyàn láti Delta
- Kefee, olori obinrin ati ko-orin Naijiria
 - Sunny Ofehe, olóṣèlú àti ajàfún òmìnira
 - Isaiah Ogedegbe, kọrinaọmọ orílẹ̀ èdè Nàíjíríà[4]
 
| Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ.  | 
Àwọn Ìtọ́kasí
Wikiwand - on
Seamless Wikipedia browsing. On steroids.
Remove ads
