Ayé, tàbí Ilé-ayé ni ilé asán ilé tó kún fún wàhálà àti ìpayínkeke, ilé ayé le gan pẹ̀lú walaha àfi kí elédùmarè ọba ṣàánú wa ni. Bákan náà Nàìjíríà tí ó jẹ́ ìlú ti a wà yìí kò rọgba rárá, wàhálà ló tún lọ sí, kò sì epo, kò sì owó kò sì oúnjẹ. Ilé ayé jẹ́ pílánẹ́ẹ̀tì kẹta sí òòrùn, ó sì jẹ́ èyí tí ó tóbi jùlo nínú àwọn pílánẹ́ẹ̀tì tí wọ́n ní ilẹ̀ tí ó ṣe é tẹ̀.
Ilé-ayé jé pílánẹ́ẹ̀tì àkọ́kọ́ tí ó ní omi tó ń sàn ní orí rẹ̀. Bẹ́ẹ̀ sìni Ilé-ayé nìkan ni pílánẹ́ẹ̀tì tí ìwádìí fidi rẹ múlẹ̀ [17] pé o ní ojú-òrun (atmosphere) tí o jẹ́ kìkì nitrogen àti oxygen tí ó ń dà àbò bo ilé-ayé lọ́wọ́ àtaǹgbóná (radiation) tó léwu sí ènìyàn. Bákan náà ojú-òrun kò gba àwọn yanrìn-òrun láàyè láti jábọ́ sí ilé-ayé nípa sísun wọ́n níná kí wọ́n ó tó lè jábọ́ sí ilé-ayé. [7]