Ìṣiṣẹ́òkòwò

From Wikipedia, the free encyclopedia

Ìṣiṣẹ́òkòwò
Remove ads

Ìṣiṣẹ́òkòwò (Economics) je sayensi awujo to unmo nipa imuwaye, ipinkiri, ati iraja awon oja ati iwofa.

Thumb
Ọ̀rọ̀ òkòwò un ka nipa ipinu idunadura, imuwaye ati iraj, bi eyi to un sele ni oja.

Ọ̀rọ̀ òkòwò un se alaye bi awon okowo se unsise ati bi awon osise olokowo se un wuwa si ara won. Ituyewo olokowo unje mimulo kakiri awujo, ninu isowo, inawo ati ijoba, sugbon bakanna ninu iwa odaran,[1] eko,[2] the ebi, ilera, ofin, iselu, esin,[3] social institutions, war,[4] ati sayensi.[5]

Remove ads

Itokasi

Loading related searches...

Wikiwand - on

Seamless Wikipedia browsing. On steroids.

Remove ads