Eku ti odò
From Wikipedia, the free encyclopedia
Remove ads
Eku ti odò ganganrangan (beaver)

Eku ti odò kékèré (water rat)
Boye e n béèré kini idi awa n pe won eku ti odò ganganrangan ati eku ti odò kékèré. Awa n so eku ti odò ganganrangan ati eku ti odò kékèré nitori okan ninu won je ganganrangan (o tobi) ati okan ninu won kékèré.
Eku ti odò ganganrangan
Eku ti odò ganganrangan ni ehin ti o tobi gan, ehin re won ma hù kiakia, ati eku ti odò ganganrangan feran lati gé awon igi lati ko ilé won ninu omi. Àwon eku ti odò ganganrangan, won ni iru ti o gun.[1]
Eku ti odò kékèré
Wikiwand - on
Seamless Wikipedia browsing. On steroids.
Remove ads