Gàbọ̀n

From Wikipedia, the free encyclopedia

Gàbọ̀n
Remove ads

Gàbọ̀n (play /ɡəˈbɒn/; ìpè Faransé: [ɡabɔ̃]), lonibise bi Orile-ede Olominira ara Gabon (Faransé: République Gabonaise) je orile-ede ni iwoorun gbongan Afrika to ni bode mo Guinea Alagedemeji ni ariwaiwoorun, Cameroon ni ariwa, ati mo Orile-ede Olominira ile Kongo to lopo ni ilaorun ati guusu. Ikun-omi Guinea, apa Okun Atlantiki si iwoorun. Ile re tobi to 270,000 km² o si ni alabugbe to to 1,500,000. Oluilu ati ilu totobijulo re ni Libreville.

Quick facts Orílẹ̀-èdè Olómìnira ará Gàbọ̀nGabonese Republic République Gabonaise, Olùìlú àti ìlú tótóbijùlọ ...

Lati igba ilominira latowo Fransi ni August 17, 1960, awon aare meta loti joba ni Gabon. Ni arin ewadun 1990, Gabon bere sistemu egbe oloselu pupo ati isepo oloselu tuntun to fi aye gba igbese aladiboyan kedere to si satunse opo awon ise ijoba. Gabon ti je omo-egbe alaije tigba gbogbo ni Igbimo Abo UN fun igba 2010-2011.

Low Isupo alabugbe kekere lapapo mo opo awon ohun alumoni ati idawosi aladani okere ti so Gabon di ikan ninu awon orile-ede to jomitoro julo ni Afrika, pelu HDI to gajulo[4] ati GDP ti enikookan togajulo keta (PPP) (leyin Equatorial Guinea ati Botswana) ni agbegbe yi.

Remove ads

Itokasi

Loading related searches...

Wikiwand - on

Seamless Wikipedia browsing. On steroids.

Remove ads