Gíríìsì

From Wikipedia, the free encyclopedia

Gíríìsì
Remove ads

Gíríìsì (English: /ˈɡriːs/  ( listen); Gíríkì: Ελλάδα, Elláda, IPA: [eˈlaða]  ( listen); Èdè Grííkì Ayéijọ́un: Ἑλλάς, Hellás, IPA: [helːás]), bakanna gege bi Hellas ati fun ibise bi Helleniki Olominira (Ελληνική Δημοκρατία, Ellīnikī́ Dīmokratía, IPA: [eliniˈci ðimokraˈtia]),[9] je orile-ede kan ni guusuapailaorun Europe, o budo si apaguusu opin Balkan Peninsula. Griisi ni ile bode mo Albania, Olominira ile Makedonia ati Bulgaria si ariwa, ati Turki si ilaorun. Okun Aegeani dubule si ilaorun re, the Okun Ioniani si iwoorun, ati Okun Mediterraneani si guusu. Griisi ni o ni etiodo kewa togunjulo ni agbaye toje 14,880 km (9,246.00 mi) ni gigun, ti o ni opolopo iye awon erekusu (bi 1400, 227 ni ibi ti aon eniyan ngbe), ninu won ni Crete, Dodecanese, Cyclades, ati awon Erekusu Ioniani. Bi ogorin ninu ogorun ile Griisi ni o je ti awon oke, ninu ibi ti Oke Olympus ni o gajulo to je 2,917 m (9,570.21 ft).

Quick Facts Orílẹ̀-èdè Olómìnira Hẹ́llẹ́nẹ̀ Hellenic Republic Ελληνική ΔημοκρατίαEllīnikī́ Dīmokratía, Olùìlú àti ìlú tótóbijùlọ ...

Griisi oni fa gbongbo de asa-olaju Griisi ayeijoun, nibi ti gbogbo eniyan gba bi ibusun asa-olaju Apaiwoorun. Nitori eyi o je ibi ibere oseluaralu,[10] imoye Apaiwoorun,[11] Awon Idije Olympiki, litireso Apaiwoorun ati itankiko, sayensi oloselu, awon ipile sayensi ati mathematiki pataki, ati drama,[12] ati trajedi ati awada. Asesile yi han gedegbe ninu awon Ibi Oso Agbaye UNESCO 17 ti won wa ni Griisi.

Griisi je orile-ede adagbasoke to ni Human Development Index giga,[13][14][15][16] Griisi ti je omo egbe Isokan Europe lati 1981 ati Isokan Okowo ati Owonina Europe lati 2001,[17] NATO lati 1952,[18] ati Ile-ise Ofurufu Europe lati 2005.[19] Bakanna o tun je omo egbe latibere Isodokan awon Orile-ede, OECD,[20] ati Agbajo Ifowosowopo Okowo ni Okun Dudu. Atensi ni oluilu re; awon ilu pataki miran nibe tun ni Thessaloniki, Patras, Heraklion ati Larissa.

Remove ads

Awon Periferi ati ibile

Fun amojuto, Griisi ni periferi metala ti won je pipin si ibile mokaleladota ([nomoi] error: {{lang}}: text has italic markup (help), singular Gíríkì: nomos). Bakanna ni agbegbe idawa kan wa to n je Oke Athos (Gíríkì: Agio Oros, "Oke Mimo"), to ni bode mo periferi Central Macedonia.

More information Map, Number ...



Remove ads

Itoka

Loading related searches...

Wikiwand - on

Seamless Wikipedia browsing. On steroids.

Remove ads