Èdè Húngárì
From Wikipedia, the free encyclopedia
Remove ads
Ede Hungari, tabi Magyar (magyar nyelv, hu), ni o je eka ede Ugric language ti o wa lati ara of ede Uralic language ti won so ni orile-ede Hungary ati awon agbegbe re. Ede yi je ede amulo gbogbo gboo ni orile-ede naa yan laayo, o si wa Lara awon ede ti o gbajumo julo ninu awon ede merinlelogun ti won wa ni apa ile Yuroopu. Yato si orile-ede Hungary, won tun n so ede yi ni ariwa Slovakia, iwo oorun Ukraine (Transcarpathia), ati aarin gbungbun Romania (Transylvania), pelu Serbia (Vojvodina), Croatia, Slovenia (Prekmurje), ati awon apa ibikan in ile Austria (Burgenland).

![]() |
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |
Remove ads
Awon itokasi
Wikiwand - on
Seamless Wikipedia browsing. On steroids.
Remove ads