Hydrogen

From Wikipedia, the free encyclopedia

Hydrogen
Remove ads

Háídrójìn tabi Hídrójìn (pípè /ˈhaɪdrɵdʒɨn/,[6] HYE-dro-jin) je elimenti kemika to ni nomba atomu 1. O je sisoju fun latowo ami-idamo H. Pelu iwuwo atomu iye 1.00794 u (1.007825 u fun Hydrogen-1), hydrogen ni apilese kemika tofuyejulo ati tolopojulo, o je bi 75 % gbogbo isupo apilese Agbalaaye.[7] Awon irawo ninu telentele olori je ni pataki kiki haidojin ni iwa plasma re. Ki haidrojin o da wa fun ra ara re ni Aye sowon gan.

Quick facts Háídrójìn, Ìhànsójú ...
Idanwo Hydrogen julọ.Oniranran



Remove ads

Itokasi

Loading related searches...

Wikiwand - on

Seamless Wikipedia browsing. On steroids.

Remove ads