Irène Joliot-Curie
From Wikipedia, the free encyclopedia
Remove ads
Irène Joliot-Curie (12 September 1897 – 17 March 1956) je onimo sayensi ara Fransi, ohun ni omobinrin Marie Skłodowska-Curie ati Pierre Curie ati iyawo Frédéric Joliot-Curie. Lokanna mo oko re, Joliot-Curie gba Ebun Nobel fun Kemistri ni 1935 fun iwari won iranna afowose. Eyi so ebi Curie di ebi to ni awon elebun Nobel julo titi doni.[1] Bakanna awon omo mejeji awon Joliot-Curies, Hélène ati Pierre na je onimo sayensi pataki.[2]
![]() |
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |
Remove ads
Itokasi
Wikiwand - on
Seamless Wikipedia browsing. On steroids.
Remove ads