Itọ́

From Wikipedia, the free encyclopedia

Itọ́
Remove ads

Itọ́ ni omi ara tí ó ń sun láti ibùsun kan nínú ẹnu yálà lára ènìyàn tàbí ẹranko. Lára ènìyàn, itọ́ tí ó ń sun tó ìdá 99.5 omi pẹ̀lú (electrolytes), kẹ̀lẹ̀bẹ̀, ẹ̀jẹ̀ funfun, epithelial cells níbi tí DNA ti ma ń sun jáde.[1] [2]

Thumb
Speech saliva aerosols emission

Iṣẹ́ tí itọ́ ń ṣe

Itọ́ ma ń ṣiṣẹ́ gẹ́gẹ́ bí ìbomirin ẹnu, rínrin óúnjẹ ó sì tún ma ń ṣiṣẹ́ ìgbémì, tí ó sì tún ń ìrọ̀rùn ìgbé ọ̀rọ̀ jáde kí ẹnu ó má ba gbẹ.[3] [4] [5]

Àwọn Ìtọ́ka sí

Loading related searches...

Wikiwand - on

Seamless Wikipedia browsing. On steroids.

Remove ads