Johannes Kepler

From Wikipedia, the free encyclopedia

Remove ads

Tani Johannes Kepler?

Quick Facts Ìbí, Aláìsí ...

Johannes Kepler (Pípè nì Jẹ́mánì: [ˈkɛplɐ]; December 27, 1571 – November 15, 1630) je ara Jemani onimo mathimatiki, atorawo ati aworawo, ati eni orundun 17k pataki ninu ijidide sayensi. O gbajumo fun awon ofin igbera planeti to ni oruko re, ti awon atorawo ojowaju seloroami, ti won da le ori awon iwe re Astronomia nova, Harmonices Mundi, ati Epitome of Copernican Astronomy. Awon ise inu awon iwe yi na tun ni won je ipilese fun ero ifamora alagbalaaye ti Isaac Newton.

Remove ads
Loading related searches...

Wikiwand - on

Seamless Wikipedia browsing. On steroids.

Remove ads