John Adams

Olóṣèlú From Wikipedia, the free encyclopedia

John Adams
Remove ads

John Adams je oloselu omo ile Amerika. Wọ́n bí Adams ní 1735. Ó kú ní 1826. Òun ni ó jẹ President ilẹ̀ Àméríkà lẹ́yìn Washington. Òun ni ó kọ́kọ́ lọ ṣe ambassador ilẹ̀ oní-republic tuntun yìí ní ilẹ̀ Gẹ̀ẹ́sì.

Quick facts 2nd President of the United States, Vice President ...


Remove ads

Itokasi

Loading related searches...

Wikiwand - on

Seamless Wikipedia browsing. On steroids.

Remove ads