Joseph Louis Lagrange

From Wikipedia, the free encyclopedia

Joseph Louis Lagrange
Remove ads

Joseph-Louis Lagrange (25 January 1736, Turin, Piedmont – 10 April 1813, Paris), abiso Giuseppe Lodovico (Luigi) Lagrangia, je onimo mathimatiki ati atorawo to je bibi ni Itali, sugbon to gbe apa igbesiaye re kan ni Prussia ati apa kan ni Fransi, to se ipa pataki si gbogbo papa ituwo, si iro nomba, ati si isiseero ologbologbo ati orun. Pelu itileyin Euler ati d'Alembert, ni 1766 Lagrange ropo Euler gege bi oludari mathimatiki ni Akademi awon Sayensi Prussia ni Berlin, nibo to wa fun odun toju ogun lo, to si ko opo iwe ati to si gba orisirisi ebun latowo Akademi awon Sayensi Fransi. Aroko Lagrange lori isiseero alatuwo (Mécanique Analytique, 4. ed., 2 vols. Paris: Gauthier-Villars et fils, 1888-89), to ko ni Berlin ati to je kikoko tejade ni 1788, lo sagbesile iwo lekunrere julo lori isiseero ologbologbo leyin Newton, o si se ipilese fun igbedagba fisiksi onimathimatiki ni orundun kokandinlogun.

Quick facts Ìbí, Aláìsí ...



Remove ads

Itokasi

Loading related searches...

Wikiwand - on

Seamless Wikipedia browsing. On steroids.

Remove ads