Kofi Annan
From Wikipedia, the free encyclopedia
Remove ads
Kofi Atta Annan ( 8 April 1938 - 18 August 2018) je omo orile-ede Ghana to je diplomati to wa ni ipo gege bi Akowe Agba keje Agbajo Iparapo awon Orile-ede lati 1 January 1997 de 31 December 2006. Annan ati Agbajo Iparapo awon Orile-ede jo gba Ebun Nobel fun Alafia ni 2001.
Remove ads
Itokasi
Wikiwand - on
Seamless Wikipedia browsing. On steroids.
Remove ads