Konrad Adenauer

Olóṣèlú Ọmọ Orílẹ̀-èdè Germany. From Wikipedia, the free encyclopedia

Konrad Adenauer
Remove ads

Wọ́n bí Konrad Adenauer ní 1876. Ó kú ní 1967. Òun ni Chancellor West German Federal Republic ní 1949 sí 1963. Òun ni ó dá Christain Democratic Party sílẹ̀ òun sì ni alága rẹ̀ láti 1945 títí di 1966. Lẹ́yìn ìgbà tí wọ́n ti ṣẹ́gun Jẹ́mánì tán, ó fún Jẹ́mánì ní òfin (Constitution) tí ó fi ni lọ́kàn balẹ́ Ó sì jẹ́ kí àwọn ìlú Òyìnbó yòókù fún Jẹ́mánì láyè nínú ẹgbẹ́ àfọwọ́sowọ́pọ̀ (Western Alliance) wọn. Ó sa gbogbo agbára láti jẹ́ kí ìparí ìjà wà láàrin ilẹ̀ Fransi àti Jẹ́mánì ṣùgbọ́n kò fi àyè (accommodation) gba Rọ́síà.

Quick facts Chancellor of Germany, Ààrẹ ...
Remove ads

Itokasi

Loading related searches...

Wikiwand - on

Seamless Wikipedia browsing. On steroids.

Remove ads